Jesu Akọni mi/Jesus My Hero: Yoruba Bilingual Translation (Jesus My Hero: A Christ-Focused Children's Book on Faith, Fear, and Unconditional Love - Multilingual)

ISBN: 9781091393264
$10.50
1091393265

Lẹyin Halloween ni ọdun to kọja, ọmọ mi Ivan, ọmọ ọdun meji ṣaa deede bẹẹrẹ si ni bẹru ẹmi adẹrubaniyan nigbati o ba wa ninu okunkun. O bẹẹrẹ si ni isoro lati sun laalẹ. Yio ji ni ọpọlọpọ igba- pẹlu omi ẹkun – yio maa wipe: ”Adẹrubaniyan …Ẹru n bami…”Nitori eleyi, emi ati ọkọ mi gbiyanju ni gbogbo ọna lati ṣalaye nipa Jesus Kiristi fun n sugbọn ko ye e. Nitoribẹ, mo pinnu lati ṣe iwe awọn ọmọde, eyi ti o mu u rọrun lati mọ ẹniti Jesu jẹ. Iwe naa ni a pe ni “Jesu Akọni Mi” nitoripe, O ku lori agbelebu fun ẹṣẹ wa ti O si GBA WA LA lọwọ iparun ayeraye. Oun ni akọni didara julọ! Iwe naa jẹ abala marun (oju ewe mẹwa) nitoribẹ o se e ka ni alaalẹ fun awọn ọmọ wa. Ati wipe nigbati wọn ba dagba to o, wọn le e ka fun ra a wọn! 

You have successfully subscribed!